Aare Buhari ati awon agbagba ninu egbe oloselu APC peju sibi iwode itagbangba egbe oloselu APC

0

Aare Buhari ati awon agbagba ninu egbe oloselu APC peju sibi iwode itagbangba fun eto idibo fun oludije fun ipo Gomina ipinle Osun Gboyega Oyetola ni ilu Osogbo.

Idunu ati ayo ni Gomina ipinle na Ogbeni Rauf Aregbesola fi ki won kaabo si ipinle na, o si fi da won loju wipe igbaradi to peye tin lo lori eto idibo na.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply