Aare Buhari ti de orilede America lati gbaradi fun ipade re pelu Aare orilede na, Donald Trump

0

Aare Buhari loni ti de de ilu Washinton ni orilede America fun igbaradi ipade re pelu Aare orilede America, Donald Trump ti yo waye ni ogbon ojo osu kerin. Opolopo awon ogbontarigi eyan ati awon afinju onisowo bi Aliko Dangote ati awon bebe lo, lo tele Aare na lati lo se ipade yi.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply