Aare Buhari ti yi ayajo ojo odun ijoba alagbada pada si ojo kejila osu kefa (June 12)

0

Aare Buhari loni ti se atejade kan lati fi han wipe ohun ti fowo si iwe lati yi ayajo ojo odun ijoba alagbada lati ojo kokandinlogbon osu karun si ojo kejila osu kefa. O so siwaju si wipe ijoba apapo si ti pinu lati fun oloye Moshood Kashimawo Abiola (MKO) ni ami eye fun akitiyan re lori igbeleke oselu ati ijoba alagbada ni orilede Nigeria.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply