Aare Buhari tun ti rin irinajo lo si orilede United Kingdom lati lo mojuto ilera re

0

Ninu atejade kan ti Aare Buhari agbenuso re ogbeni Garba Shehu se, iroyin fi to wa leti wipe Aare Buhari tun ti gun le irinajo olojo merin lati lo mojuto eto ilera re ni orilede United Kingdom. Ojo kejila osu karun ni yo pada de.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply