- 166shares
- 165Facebook
- 0Twitter
- 0Pinterest
- 0LinkedIn
- 0Email
- 0Reddit
Leyin ogorun ojo ti Aare Mohamoodu Buhari ti kuro ni orilede Nigeria lati lo gba itoju to peye ni ilu London, adupe wipe aare ti pada de layo ati alafia. Oko baalu aare na lo ba ni papako ofurufu Nnamdi Azikwe international airpot ni nkan bi ago merin abo osan oni (4;30pm).
Opolopo awon ololufe re lo peju si papako ofurufu na lati ki aare ka bo.
Get more stuff like this
in your inbox
Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.
Thank you for subscribing.
Something went wrong.
E kaabo oo
E seun.
London use ekabo
A dupe.
U are wlcm
Alihamdulilah
Adupe.
Won so potiku, iro lenpa, won so porolapa iro lenpa, won so porolese iro lenpa. BABA BUHARI ko ku o. Iro nlaa