Ajo ASUU ti gun le iyanselodi (strike).

0

Gege bi atejade ti Aare ajo egbe awon oluko ile iwe giga ASUU ogbeni Biodun Ogunyemi se loni ojo kerinla osu kejo, o so wipe awon ti gun le iyanse lodi latari ai mu ileri se ijoba apapo lori eto eko ati itoju awon oluko ile iwe giga. O se ikilo fun gbogbo awon oluko ati osise ile iwe giga patapata wipe won o gbodo lo si ibi ise rara ayafi ti awon ton se imojuto eto eko orilede ba wa lati ba won so aso yepo to mu ina dako.

O so si waju si wipe opolopo owo osu awon oluko ni ijoba apapapo ko lati san, ti won si ti ko lati ma se itoju fun awon oluko agba. O so wipe idi eyi ni awon fi pinu lati yan ise lodi, ti awon o si ni pada si enu ise afi igba ti ijoba apapo ba da awon lohun.

 

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply