Alhaji Tekno ati Alhaja Lola Rae, ki lon sele gangan?

0

Leyin gbogbo atotonu ati afihan awon aworan to toka si wipe odomode olorin Tekno ati odomodebirin olorin Lola Rae n’ta omi oge si ra won lara,o fe jo wipe ija ti be si le laarin awon ololufe mejeji yi.

Iwadi fi ye wa wipe Alhaja Lola Rae ati Alhaji Teko ti ko ara won gege bi ore lori ero ayelujara instagram.

Eyi lon mu ibere wa wipe ki lon sele gangan?

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply