Awon meta lo ku, ti awon meje si farapa ninu ikolu ti awon omo egbe agbesunmomi Bokoharam se ni ilu Maiduguri.

0

Awon omo egbe agbesunmomi Bokoharam lale ana lo se ikolu ni ilu Maiduguri nibi ti awon eyan meta ti so emi won nu, ti awon meje si farapa. Gege bi atejade ti awon ti oro na se oju won se, won so wipe awon odaran na yabo ilu Koffa, won si bere sini yin ibon, leyin eyi ni won fi ina si awon ile won.

Awon agbofinro ti wa bere iwadi lati mo awon amokun seka na, ki won si fi oju ba ile ejo.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply