Aworan gbajugbaja osere kunrin Jim Iyke nibi to tin yo omi Garri (unirate) ti da gobe sile o.

0

Osere kunrin Jim Iyke, lo se afihan aworan yi nibi to ti n se igbonse (unirate) ni egbe titi. Awon ololufe re kan lori itakun ayelujara instagram so wipe iwa itiju ati iwa buruku gba ni iwa na, ti ko si ye fun omoluabi lati ma se. Oserekunrin na, leyin igba to da oro na ro, o toro aforiji lowo awon ololufe re sugbon o so wipe ohun o se ileri fun won wipe ohun o tun ni se ni ojo miran.

E gbo, kini eyin ro, se iwa to boju mu ni? abi iwa buruku ni?

Aworan ati atejade to se lati toro aforiji ni yi ni ede geesi;

 

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply