BA TI FE KO RI, BE NA LO RI EMI LA O NI YO SI?…. Gbajugbaja oserebirin Funke Akindele Jenifa ti Loyun.

0

Gbajugbaja oserebirin Funke Akindele, eni ti gbogbo eyan mon si Jenifa ti loyun. O se afihan ikun re to se rumu-rumu nibi ayeye ipate Glo-lafta Fest to waye ni osan oni ni agbegbe Festac Town ni ipinle Eko.

Inu wa dun, ayo wa si kun wipe iru orire bayi wole to arabirin Funke ati oko re JJC wole wa, Adura wa ni wipe, Olorun o so omo na kale ni alafia. Amin.

Eku orire o.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply