EBUKA ALAGBADA INA.

0

 

Nibi ayeye igbeyawo Banky W ati Adesuwa Etomi, agbada gbajugbaja osere ati soro-soro EBUKA tayo laarin awon akegbe re. Egan ni e, eni keni to ba ri agbada arakunrin na ti ko ba beri, a je wipe oju n’dun iru eni be ni.

Gbogbo awon eyan lo kan sara si eni to ran aso arakunrin na ti won si ki ku ise. Eyi lo mu awa na fun arakunrin na ni oruko alagbada ina.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply