Egbe agbaboolu Arsenal ti fo’rijagbo leyin igba ti Egbe agbaboolu Nottingham Forest foju won ri mabo ninu idije FA cup to waye lana.

0

Egbe agbaboolu Arsenal fidi remi lana ninu idije FA CUP to waye laarin akegbe won Nottingham Forest. Omi ayo merin si meji (4-2)ni awon egbe agbaboolu Arsenal je ti won si mu omi si. Agbaboolu Eric Lichaj, Per Mertesacker, Ben Brereton ati Kieran Dowell lo gba omi ayo wole fun egbe agbaboolu Nottingham forest, ti Ben Brereton ati Danny Welbeck si gba omi ayo wole fun Arsenal.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply