Gbajugbaja odomodebirin olorin Tiwa Savage ti fakoyo nigba to gba emi eye nibi ayeye MTV European Music Awards

0

Odomodebirin olorin Tiwa Savage ti gbegba oroke nibi ayeye MTV European Music Awards nigba to fakoyo, to si gba ami eye eni to mo orin ko julo nile adulawo (Best African Act) .

Odomodebirin na fi idunu ati ayo re han nigba to se awon afihan aworan kan lori ero ayelujara instagram re, o dupe lowo awon ololufe re, o si dupe gidigidi lowo Olorun fun ife ati aseyori ton ri gba lojojumo.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply