Gomina ipinle Eko, Akinwumi Ambode ti pase wipe ki gbogbo awon ile eko ti ijoba ati aladani ni ipinle na ma ko awon akeko ni orin adako orilede (National Anthem) ni ede Yoruba.

1

Gomina ipinle Eko, Akinwumi Ambode ti pase wipe ki gbogbo awon ile eko ti ijoba ati aladani ni ipinle na ma ko awon akeko ni orin adako orilede (National Anthem) ni ede Yoruba. O so eleyi lati ri wipe awon omo bibi ile Yoruba o padanu eko ati imo ede Yoruba. O so siwaju si wipe akeko ti ko ba ti pegede ninu ede Yoruba ko gbodo tesiwaju ninu eko re.

 

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Previous articleWhen it comes to team work, a leader must not be afraid to shine
Next articleI am Woman
My name is Adenle Kolade Samuel, I am a Yoruba news and lifestyle Blogger,Owner of www.kollymoore.blogspot.com. Studied Linguistics and Nigerian Languages at University of Ilorin,graduated in 2014, currently studying Mass communication in Kwara State University. I started blogging in 2015 with the passion and love for Yoruba language. I want everyone to know that there is uniqueness in being real and truthful to yourself and that God has given everyone a duty to promote his/ her culture.

1 COMMENT

Leave a Reply Cancel reply