Ija dopin, ogun si tan laarin Davido ati Wizkid.

2

Ija olojo pipe laarin gbajugbaja odomode olorin Wizkid ati akegbe re Davido lana ti pari ni bi ipade orin ti Wizkid gbe kale to waye ni ile itura Eko Hotel ni ipinle Eko.  Iyalenu nla lo je fun gbogbo eyan nigba ti Wizkid pe Davido jade ti won si fo ko orin FIA-FIA eyi ti Davido sese ko. 


Orisirisi iha ni awon ololufe won ko si isele kayefi ati aramonda yi,ti opolopo awon eyan si ti se orisirisi atejade lori ero ayelujara twitter, instagram ati Facebook.  Awon atejade na ni yi;

 

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

2 COMMENTS

Leave a Reply Cancel reply