Meji ninu awon omobirin chibok to salo mo awon agbesunmomi Bokoharam lowo, lo se ipade pelu Aare orilede America Donald Trump

1

Joy Bishara , omo ogunodun (20yrs), ati Lydia Pogu ,omo odun kokandinlogun (19yrs) meji ninu awon omobirin chibok to salo mo awon agbesunmomi Bokoharam lowo ni odun 2014 ni won lo se ipade pelu Aare orilede America Donald Trump ni ana ojoru, ojo kejidinlogbon osu yi ni White House.

Awon omobirirn meji yi ni ori ti sun bare leyin isele to sele na, nigbati awon oni inu ire kan ti mu won lo si ile iwe Canyonville Christian Academy ti won si ti keko jade. Osu ton bo ni won o bere eko won ni ile iwe eko giga Southeastern University ni Florida.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

1 COMMENT

Leave a Reply Cancel reply