Mo ti se tan lati di Aare orilede Nigeria ni odun 2019. Ogbeni Omoyele Sowore

0

Alase ati oludari Sahara reporters Mr Omoyele Sowore ti pada wa si orilede Nigeria leyin igba to fi ipinu re han lati di Aare orilede Nigeria ni odun 2019.
Ogbeni Sowore nigba ton ba awon akoroyin soro, lo so wipe igbaye-gbadun, itesiwaju ati idagbasoke awon omo bibi orilede Nigeria paapa julo awon odo ati awon obirin lo je ohun logun julo. O so siwaju si wipe ohun ti setan lati gbe orilede Nigeria si gbedeke awon orilede toti lami-laka ni agbaye, wipe ohun si ti se tan lati gba agbara lowo awon ton fi agbara ati ipo yan awon omo bibi orilede Nigeria je.
O wa ro gbogbo eyan lati lo gba kadi idibo won, ki won si fowo sowopo pelu oun.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply