Olori Alaafin Oyo, (IKU BABA-YEYE) tun ti bi ibije lanti-lanti

0

Epo n’be Ewa n’be ni orin ti won ko ni aafin Alaafin Oyo (Iku baba-yeye) lati ibere odun yi. Eyi waye latari awon omo ibeji ti awon olori laafin tin bi.

Olori Anu ni olori to tun sese bi ibeji, leyin ti olori Memunat Adeyemi ati Olaitan Ajoke na gbe ibeji won nu aafin na ni nkan bi osu mejo seyin.

Eku orire o.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply