Olu (oba) ti Warri ti fi Ayirimi Emami je oye igbakeji adari awon Itsekiri.

0

Olu ti Warri, HRM Ogiame Ikenwoli ti fi Oloye Ayiri Emami je oye Ologbotsere (Prime Minister) ti ilu Warri. Oye yi lo je ki Ayiri Emami je enikeji tabi igbakeji si Oba ilu Warri. Idunu ati ayo ni arakunrin na fi gba oye yi.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply