Oni ni ayeye ojo ibi odun kárùndínlọ́gọ́rin (75years) ti Aare Buhari.

0

Aare orilede Nigeria Muhamodu Buhari ti loni ojo ketadinlogun osu kejila odun 2017 pe omo odun márùndínlọ́gọ́rin (75years). Adura wa ni wipe ki olorun fun baba na ni ogbon, imon ati oye lati le gbe orilede Nigeria de ipo giga. Amin. Eku ojo ibi o Sai Baba.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply