Orilede Faranse ti gba ife eye agbaye fun odun 2018 leyin igba ti won na orilede Croatia ni omi ayo merin si meji (2-1)

0

Orilede Faranse ti gba ifi eye agbaye fun odun 2018 leyin igba ti won na orilede Croatia ni omi ayo merin si meji (2-1) ninu idije ifesewonse to waye ni orilede Russia loni.

Ifewonse na gbona pupo ti awon agbaboolu fun orilede mejeji yi si fakoyo. Ogbeni Paul Pogba, Mbappe ati Antoine Griezmann lo gba awon omi ayo na wole fun orilede faranse, ti Ivan Perisic ati Mandzukic si gba omi ayo meji wole fun orilede Croatia.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply