#Worldcup2018; Egbe agbaboolu Croatia na egbe agbaboolu Super Eagles ni omi ayo meji si odo (2-0) “Oro pa esi je”

0

Ibanuje nla lo je fun egbe agbaboolu Super Eagles ati awon ololufe won nigba ti iko egbe agbaboolu Croatia gbomi ewuro si won loju ninu ikolu to waye nibi idije World cup ni ale oni.

Ogbeni Luka Modric ati Oghenekaro Etebo (super eagles) lo gba omi ayo na mejeji wole, ti Super Eagles o si ri ikankan da pada.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply