Yusuf omokunrin kan soso Aare Buhari farapa ninu isele ijamba okada ni ale ana.

17

Omokunrin kan soso ti Aare Buhari bi Yusuf farapa yanana ninu ijamba okada kan to waye lana ni ale ana ojo kerindinlogbon osu kejila odun yi. Iwadi fi ye wa wipe ile iwosan Cedacrest Hospital ni ilu Abuja, ni won gbe arakunrin na lo fun itoju.

  Ogbeni Femi Adesina nigba ton fi idi oro na mule ninu atejade kan to se ni ede geesi lori ero ayelujara twitter so wipe ara odomodekunrin na tin bo sipo, o si duoe lowo gbogbo awon omo Nigeria fun ife won.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

17 COMMENTS

  • Leave a Reply Cancel reply