Yoruba News

Alai mo ore lasan-lasan ni ‘K1 De Ultimate’- Obesere lo so be

Gbajugbaja olorin Fuji ati ogbontarigi osere tiata Abass Akande Obesere ninu atejade kan to se lori oro ija to waye…

Ogbeni Fela Durotoye ti gba iwe ase lati egbe oloselu ANN lati tesiwaju ninu ipinu re lati dije fun ipo Aare ni odun 2019

Oludije fun ipo Aare, Ogbeni Fela Durotoye ti gba iwe ase lati egbe oloselu ANN lati tesiwaju ninu ipinu re…

Aare Buhari ati awon agbagba ninu egbe oloselu APC peju sibi iwode itagbangba egbe oloselu APC

Aare Buhari ati awon agbagba ninu egbe oloselu APC peju sibi iwode itagbangba fun eto idibo fun oludije fun ipo…

Owo ti ba oloselu agba ni ipinle Osun, Timothy Owoeye nibi to tin we laarin oja

Owo awon ara ilu ti ba oloselu agba ati asoju ijoba ipinle Ilesa West ni ile igbimo asofin ti ipinle…

Amir, omo Sultan ti ilu Sokoto ti farapa ninu ijamba oko

Isele ijamba oko kan to waye ni nkan bi ago mejila ni iroyin fi to wa leti wipe Amir, omo…

Awon agbebon kan ti ji ojise Olorun ijo Katoliki mimo kan gbe ni ipinle Delta

Ojise Olorun Christopher Ogaga ti ijo Katoliki mimo Emmanuel Catholic Church Oviri-Okpe ni ilu Okpe, ipinle Deltani iroyin fi to…

Temi, omobirin ogbontarigi onisowo Femi Otedola ti keko jade ni ile iwe giga University College London

Ninu atejade ati afihan awon aworan ti gbajugbaja ati ogbontarigi onisowo Femi Otedola fi han lori ero ayelujara instagram, o…

Awon eyan merinla ti so emi won nu ninu ikolu to waye ni ipinle Plateau

Awon Fulani daran-daran ni ana ojo keji osu kesan se ikolu tuntun ni agbegbe Jos South ati ijoba ipinle Bassa…

Asoju Aare Yemi Osinbajo ti se atejade kan lati se atupale ati atunto ajo SARS

Asoju Aare Yemi Osinbajo loni ti se atejade kan lati se atunto patapata ajo Special Anti-Robbery Squad (SARS). Atunto na…

Kosi iyato laarin Yemi Osinbajo ati Judasi – Femi Fani Kayode lo so be

Ogbeni Femi Fani Kayode ti fi ibanuje re han si oro ati atejade ti igbakeji Aare Yemi Osinbajo se nipa…