Yoruba News

Arakunrin Olubankole Wellington (Banky W) ti fi ipinu re han lati dije gege bi asoju ile igbimo asofin labe egbe oloselu Modern Democratic Party

Arakunrin Olubankole Wellington (Banky W) ti fi ipinu re han lati dije gege bi asoju ile igbimo asofinfun awon ara…

#El-Zakzaky3.5million Opuro aye ati orun ni Lai Mohammed- Reno Omokri lo so be

Ogbeni Reno Omokri ninu atejade to se lori ero ayelujara twitter loni lo ti bu enu ate lu atejade kan…

Gbajugbaja odomodebirin olorin Tiwa Savage ti fakoyo nigba to gba emi eye nibi ayeye MTV European Music Awards

Odomodebirin olorin Tiwa Savage ti gbegba oroke nibi ayeye MTV European Music Awards nigba to fakoyo, to si gba ami…

Leyin opolopo igbiyanju, Aare Buhari ti gba iwe eri idanwo WAEC (AYO ABARA TIN-TIN)

AareBuhari loni gba alejo awon oga agba ajo WAEC lati gba iwe eri idanwo WAEC re to se. Idunu ati…

Apapo egbe awon osise (NLC) ti pinu lati gun le iyanselodi lati ojo kefa osu kokanla

Ajo apapo egbe awon osise (NLC) ti pinu lati gun le eto iyanselodi lati ojo kefa osu kokanla ti ijoba…

Olori Alaafin Oyo, (IKU BABA-YEYE) tun ti bi ibije lanti-lanti

Epo n'be Ewa n'be ni orin ti won ko ni aafin Alaafin Oyo (Iku baba-yeye) lati ibere odun yi. Eyi…

Awon agbofinro ti bere iwadi lori iku omidan Seun Ajila

Leyin iku omidan Seun Ajila, eni ti won fi ipa balo ti won si da emi re legbodo ni ojo…

Aworan nibi ayeye igbeyawo laarin Ooni Ife Oba Adeyeye Ogunwusi ati ajihinrere Naomi Oluwaseyi

Ayeye igbeyawo tunutn ti waye laafin Ooni Ile Ife, Oba Adeyeye Ogunwusi leyin igba ti igbeyawo re forisanpon pelu olori…

Ajo INEC ti yan Oludije labe egbe oloselu APC Gboyega Oyetola gege bi eni to gbe igba oroke ninu eto idibo Gomina ipinle Osun

Oludije fun ipo Gomina ipinle Osun labe egbe oloselu APC ti gbe igba oroko ninu eto idibo to waye ni…

Aare ile igbimo asofin Bukola Saraki se ipade pelu Iyiola Omisore loni ni ile Ife

Aare ile igbimo asofin, Bukola Saraki loni lo se abewo ati ipade pelu oludije fun ipo Gomina ipinle Osun labe…