Enikeni to ba ni ajosepo pelu iyawo Ooni nigbakanri lai se etutu, yo fi iku ojiji se ifaje. Ifayemi Elebuibon lo so be.

Leyin gbogbo rogb odiyan to sele lori oro ija to be sile laarin Oba Adeyeye Ogunwusi ati  Olori re nigba kan ri, baba Ifayemi Elebuibon nigba ton ba iwe iroyin the SUN soro, so wipe ki se nkan tuntun lati ri Oba Yoruba to ko iyawo re sile.

O so siwaju si wipe Oba Adeyeye ko niOba Yoruba akoko ti yo ko iyawo re sile sugbon o di dadan fun olori nigbakanri na lati lo se awon etutu kan lati fo ara re mo ajijebe, okunrin ko kunrin to ba ni ajosepo yo ku iku ojiji, tabi ki aisan kolu, tabi ti oriburuku ba iru okunrin na.

O so wipe bi arabirin na ba fe se igbeyawo pelu elo miran, o gbodo lo si ibi to jina lati se igbeyawo na, ko si podo se igbeyawo alariwo.

Atejade to se ni yi ede geesi;

While noting that Ooni would not be the first Yoruba Oba to be seperated from his wife, Elebuibon stressed that marriage breakup is not very common among Yoruba Obas, ‘the wife of the Oba will be asked to consult Ifa and Ifa will give directions on how she will make the necessary atonement for her cleansing. In Yoruba tradition, a woman who has been married to a king cannot lay with any other man even if the marriage breaks up. But when the right atonements have been made, there won’t be problem’.

On the kind of problems which an Oba’s ex-wife might encounter if she refuses to undergo the traditional cleansing rites, Elebuibon said: ‘for the woman, she might not really have a problem but for any man who sleeps with a queen or marries an ex-queen without the appropriate cleansing, the man may die prematurely, he may be struck with sickness or there might be retrogression in his life’.

He explained that if an ex-queen wants to remarry, she will have to do the cleansing with her new husband. Both of them have to take part in the atonement procedures so that they won’t have any future problem.  “Any marriage she would be going into must not be elaborate. They should go far away and avoid any flamboyant wedding,” Elebuibon warned.