Yoruba News – Viva Naija https://viva-naija.com Never far from home Tue, 02 Apr 2019 18:04:31 +0000 en-US hourly 1 https://wordpress.org/?v=5.1.1 https://i2.wp.com/viva-naija.com/wp-content/uploads/2017/01/Viva_Logo__Pink_Green-e1494690750193.jpg?fit=32%2C24&ssl=1 Yoruba News – Viva Naija https://viva-naija.com 32 32 95230173 Aare orilede America nigbakan ri George Bush ti ku https://viva-naija.com/aare-orilede-america-nigbakan-ri-george-bush-ti-ku/ https://viva-naija.com/aare-orilede-america-nigbakan-ri-george-bush-ti-ku/#respond Sat, 01 Dec 2018 13:09:41 +0000 https://viva-naija.com/?p=31595 Aare Orilede America nigbakan ri George Herbert Walker Bush ti ku. Gege bi atejade ati afihan ti ikan ninu awon molebi re se, o so wipe nkan bi ago mewa ale ana ni ologbe na je Olorun ni ipe. Omo re , eni ti oun na je Aare orilede America na ri se atejade kan […]

The post Aare orilede America nigbakan ri George Bush ti ku appeared first on Viva Naija.

]]>
https://viva-naija.com/aare-orilede-america-nigbakan-ri-george-bush-ti-ku/feed/ 0 31595
Oludasile egbe Odua Peoples Congress, alagba Frederick Fasehun ti ku https://viva-naija.com/oludasile-egbe-odua-peoples-congress-alagba-frederick-fasehun-ti-ku/ https://viva-naija.com/oludasile-egbe-odua-peoples-congress-alagba-frederick-fasehun-ti-ku/#comments Sat, 01 Dec 2018 13:05:22 +0000 https://viva-naija.com/?p=31592 Alagba Frederick Fasehun eni to je oludasile egbe ajijagbara Oodua Peoples Congress ti jade laye. Omo odun metalelogorin ni alagba na ki o to je Olorun ni ipe. Iwadi fi ye wa wipe ile iwosan Lagos State University Teaching Hospital ni alagba na ku si leyin aisan ranpe kan. Adura wa ni wipe ki Olorun […]

The post Oludasile egbe Odua Peoples Congress, alagba Frederick Fasehun ti ku appeared first on Viva Naija.

]]>
https://viva-naija.com/oludasile-egbe-odua-peoples-congress-alagba-frederick-fasehun-ti-ku/feed/ 1 31592
Arakunrin Olubankole Wellington (Banky W) ti fi ipinu re han lati dije gege bi asoju ile igbimo asofin labe egbe oloselu Modern Democratic Party https://viva-naija.com/arakunrin-olubankole-wellington-banky-w-ti-fi-ipinu-re-han-lati-dije-gege-bi-asoju-ile-igbimo-asofin-labe-egbe-oloselu-modern-democratic-party/ https://viva-naija.com/arakunrin-olubankole-wellington-banky-w-ti-fi-ipinu-re-han-lati-dije-gege-bi-asoju-ile-igbimo-asofin-labe-egbe-oloselu-modern-democratic-party/#respond Sun, 11 Nov 2018 01:13:54 +0000 https://viva-naija.com/?p=31524 Arakunrin Olubankole Wellington (Banky W) ti fi ipinu re han lati dije gege bi asoju ile igbimo asofinfun awon ara Eti Osa asofin labe egbe oloselu Modern Democratic Party. Gbajugbaja osere ati olorin na lo se afihan na nibi ayeye kan to waye ni ipinle Eko. O se atejade kan lori ero ayelujara instagram re […]

The post Arakunrin Olubankole Wellington (Banky W) ti fi ipinu re han lati dije gege bi asoju ile igbimo asofin labe egbe oloselu Modern Democratic Party appeared first on Viva Naija.

]]>
https://viva-naija.com/arakunrin-olubankole-wellington-banky-w-ti-fi-ipinu-re-han-lati-dije-gege-bi-asoju-ile-igbimo-asofin-labe-egbe-oloselu-modern-democratic-party/feed/ 0 31524
#El-Zakzaky3.5million Opuro aye ati orun ni Lai Mohammed- Reno Omokri lo so be https://viva-naija.com/el-zakzaky3-5million-opuro-aye-ati-orun-ni-lai-mohammed-reno-omokri-lo-so-be/ https://viva-naija.com/el-zakzaky3-5million-opuro-aye-ati-orun-ni-lai-mohammed-reno-omokri-lo-so-be/#respond Fri, 09 Nov 2018 00:25:51 +0000 https://viva-naija.com/?p=31521 Ogbeni Reno Omokri ninu atejade to se lori ero ayelujara twitter loni lo ti bu enu ate lu atejade kan ti ogbeni Lai Mohammed se nigba ton ba awon akoroyin soro. Ninu faran na, ni a ti ri gbo wipe owo toto million meta abo naira 3.5million naira ni won fin bo adari iko Shitte […]

The post #El-Zakzaky3.5million Opuro aye ati orun ni Lai Mohammed- Reno Omokri lo so be appeared first on Viva Naija.

]]>
https://viva-naija.com/el-zakzaky3-5million-opuro-aye-ati-orun-ni-lai-mohammed-reno-omokri-lo-so-be/feed/ 0 31521
Gbajugbaja odomodebirin olorin Tiwa Savage ti fakoyo nigba to gba emi eye nibi ayeye MTV European Music Awards https://viva-naija.com/gbajugbaja-odomodebirin-olorin-tiwa-savage-ti-fakoyo-nigba-to-gba-emi-eye-nibi-ayeye-mtv-european-music-awards/ https://viva-naija.com/gbajugbaja-odomodebirin-olorin-tiwa-savage-ti-fakoyo-nigba-to-gba-emi-eye-nibi-ayeye-mtv-european-music-awards/#respond Mon, 05 Nov 2018 01:33:43 +0000 https://viva-naija.com/?p=31504 Odomodebirin olorin Tiwa Savage ti gbegba oroke nibi ayeye MTV European Music Awards nigba to fakoyo, to si gba ami eye eni to mo orin ko julo nile adulawo (Best African Act) . Odomodebirin na fi idunu ati ayo re han nigba to se awon afihan aworan kan lori ero ayelujara instagram re, o dupe […]

The post Gbajugbaja odomodebirin olorin Tiwa Savage ti fakoyo nigba to gba emi eye nibi ayeye MTV European Music Awards appeared first on Viva Naija.

]]>
https://viva-naija.com/gbajugbaja-odomodebirin-olorin-tiwa-savage-ti-fakoyo-nigba-to-gba-emi-eye-nibi-ayeye-mtv-european-music-awards/feed/ 0 31504
Leyin opolopo igbiyanju, Aare Buhari ti gba iwe eri idanwo WAEC (AYO ABARA TIN-TIN) https://viva-naija.com/leyin-opolopo-igbiyanju-aare-buhari-ti-gba-iwe-eri-idanwo-waec-ayo-abara-tin-tin/ https://viva-naija.com/leyin-opolopo-igbiyanju-aare-buhari-ti-gba-iwe-eri-idanwo-waec-ayo-abara-tin-tin/#respond Sat, 03 Nov 2018 03:21:59 +0000 https://viva-naija.com/?p=31487 AareBuhari loni gba alejo awon oga agba ajo WAEC lati gba iwe eri idanwo WAEC re to se. Idunu ati ayo ni Aare Buhari fi gba won lalejo ninu ile Ijoba towa ni ilu Abuja. Iwe eri idanwo yi lo ti fi idi re mule wipe looto ni Aare Buhari lo si ile iwe girama, […]

The post Leyin opolopo igbiyanju, Aare Buhari ti gba iwe eri idanwo WAEC (AYO ABARA TIN-TIN) appeared first on Viva Naija.

]]>
https://viva-naija.com/leyin-opolopo-igbiyanju-aare-buhari-ti-gba-iwe-eri-idanwo-waec-ayo-abara-tin-tin/feed/ 0 31487
Apapo egbe awon osise (NLC) ti pinu lati gun le iyanselodi lati ojo kefa osu kokanla https://viva-naija.com/apapo-egbe-awon-osise-nlc-ti-pinu-lati-gun-le-iyanselodi-lati-ojo-kefa-osu-kokanla/ https://viva-naija.com/apapo-egbe-awon-osise-nlc-ti-pinu-lati-gun-le-iyanselodi-lati-ojo-kefa-osu-kokanla/#respond Thu, 25 Oct 2018 10:03:50 +0000 https://viva-naija.com/?p=31481 Ajo apapo egbe awon osise (NLC) ti pinu lati gun le eto iyanselodi lati ojo kefa osu kokanla ti ijoba apapo ba ko lati fi owo kun owo osu awon osise ijoba ni orilede yi. Ninu atejade ti Aare apapo egbe awon osise Ogbeni Ayuba Wabba se, o fi han wipe iwa aibikita ijoba si […]

The post Apapo egbe awon osise (NLC) ti pinu lati gun le iyanselodi lati ojo kefa osu kokanla appeared first on Viva Naija.

]]>
https://viva-naija.com/apapo-egbe-awon-osise-nlc-ti-pinu-lati-gun-le-iyanselodi-lati-ojo-kefa-osu-kokanla/feed/ 0 31481
Olori Alaafin Oyo, (IKU BABA-YEYE) tun ti bi ibije lanti-lanti https://viva-naija.com/olori-alaafin-oyo-iku-baba-yeye-tun-ti-bi-ibije-lanti-lanti/ https://viva-naija.com/olori-alaafin-oyo-iku-baba-yeye-tun-ti-bi-ibije-lanti-lanti/#respond Tue, 23 Oct 2018 01:54:39 +0000 https://viva-naija.com/?p=31475 Epo n’be Ewa n’be ni orin ti won ko ni aafin Alaafin Oyo (Iku baba-yeye) lati ibere odun yi. Eyi waye latari awon omo ibeji ti awon olori laafin tin bi. Olori Anu ni olori to tun sese bi ibeji, leyin ti olori Memunat Adeyemi ati Olaitan Ajoke na gbe ibeji won nu aafin na […]

The post Olori Alaafin Oyo, (IKU BABA-YEYE) tun ti bi ibije lanti-lanti appeared first on Viva Naija.

]]>
https://viva-naija.com/olori-alaafin-oyo-iku-baba-yeye-tun-ti-bi-ibije-lanti-lanti/feed/ 0 31475
Awon agbofinro ti bere iwadi lori iku omidan Seun Ajila https://viva-naija.com/awon-agbofinro-ti-bere-iwadi-lori-iku-omidan-seun-ajila/ https://viva-naija.com/awon-agbofinro-ti-bere-iwadi-lori-iku-omidan-seun-ajila/#respond Tue, 23 Oct 2018 01:47:57 +0000 https://viva-naija.com/?p=31469 Leyin iku omidan Seun Ajila, eni ti won fi ipa balo ti won si da emi re legbodo ni ojo kerin osu kewa ni ile re ni ilu Akure ni awon agbofinro ti bere iwadi lori oro na, won si ti mu afesona re Ebenezer Adejimola eni ti won fura si wipe oun lo se […]

The post Awon agbofinro ti bere iwadi lori iku omidan Seun Ajila appeared first on Viva Naija.

]]>
https://viva-naija.com/awon-agbofinro-ti-bere-iwadi-lori-iku-omidan-seun-ajila/feed/ 0 31469
Aworan nibi ayeye igbeyawo laarin Ooni Ife Oba Adeyeye Ogunwusi ati ajihinrere Naomi Oluwaseyi https://viva-naija.com/aworan-nibi-ayeye-igbeyawo-laarin-ooni-ife-oba-adeyeye-ogunwusi-ati-ajihinrere-naomi-oluwaseyi/ https://viva-naija.com/aworan-nibi-ayeye-igbeyawo-laarin-ooni-ife-oba-adeyeye-ogunwusi-ati-ajihinrere-naomi-oluwaseyi/#respond Sat, 20 Oct 2018 01:20:24 +0000 https://viva-naija.com/?p=31456 Ayeye igbeyawo tunutn ti waye laafin Ooni Ile Ife, Oba Adeyeye Ogunwusi leyin igba ti igbeyawo re forisanpon pelu olori nigbakan ri Wuraola ni nkan bi odun kan seyin. Igbeyawo na waye laarin Kabiyesi na ati arabirin ajihinrere Naomi Oluwaseyi, ojise olorun ati oludasile ijo nla kan ni ilu Akure. Opolopo atotonu lo ti waye […]

The post Aworan nibi ayeye igbeyawo laarin Ooni Ife Oba Adeyeye Ogunwusi ati ajihinrere Naomi Oluwaseyi appeared first on Viva Naija.

]]>
https://viva-naija.com/aworan-nibi-ayeye-igbeyawo-laarin-ooni-ife-oba-adeyeye-ogunwusi-ati-ajihinrere-naomi-oluwaseyi/feed/ 0 31456