Leyin opolopo igbiyanju, Aare Buhari ti gba iwe eri idanwo WAEC (AYO ABARA TIN-TIN)

0

AareBuhari loni gba alejo awon oga agba ajo WAEC lati gba iwe eri idanwo WAEC re to se.

Idunu ati ayo ni Aare Buhari fi gba won lalejo ninu ile Ijoba towa ni ilu Abuja. Iwe eri idanwo yi lo ti fi idi re mule wipe looto ni Aare Buhari lo si ile iwe girama, to si se idanwo WAEC.

Aku ori ire o.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply