Culture – Viva Naija https://viva-naija.com Never far from home Sat, 17 Feb 2018 05:23:51 +0000 en-US hourly 1 https://wordpress.org/?v=4.9.4 https://i2.wp.com/viva-naija.com/wp-content/uploads/2017/01/Viva_Logo__Pink_Green-e1494690750193.jpg?fit=32%2C24&ssl=1 Culture – Viva Naija https://viva-naija.com 32 32 95230173 #bbnaija; Odomodebirin Cee C ti so akegbe re Tobi di gbewudani. (eni ire lo). https://viva-naija.com/bbnaija-odomodebirin-cee-c-ti-akegbe-re-tobi-di-gbewudani-eni-ire-lo/ https://viva-naija.com/bbnaija-odomodebirin-cee-c-ti-akegbe-re-tobi-di-gbewudani-eni-ire-lo/#respond Fri, 09 Feb 2018 02:13:01 +0000 https://viva-naija.com/?p=27338 Gege bi atejade ti awon ololufe Tobi n se lori ero ayelujara twitter, won tin ke gbajari wipe ki odomodebirin Cee C tu Tobi kale ninu igbekun to fi si. Opolopo awon eyan ton wo idije BBN lon so wipe nkan ton sele laarin awon mejeji ki se oju lasan. Awon atejade ti won se […]

Read The Entire Story Here > #bbnaija; Odomodebirin Cee C ti so akegbe re Tobi di gbewudani. (eni ire lo).

]]>
https://viva-naija.com/bbnaija-odomodebirin-cee-c-ti-akegbe-re-tobi-di-gbewudani-eni-ire-lo/feed/ 0 27338
Awon osise ajo EFCC gba posi, igba ati opolopo ogun abenugongo lowo awon odomode marundinlogun ton cha-che. (Yahoo boys). https://viva-naija.com/awon-osise-ajo-efcc-gba-posi-igba-ati-opolopo-ogun-abenugongo-lowo-awon-odomode-marundinlogun-ton-cha-che-yahoo-boys/ https://viva-naija.com/awon-osise-ajo-efcc-gba-posi-igba-ati-opolopo-ogun-abenugongo-lowo-awon-odomode-marundinlogun-ton-cha-che-yahoo-boys/#comments Tue, 06 Feb 2018 23:46:29 +0000 https://viva-naija.com/?p=27325 Awon osise ajo Economic and Financial Crimes Commission, EFCC, ti ipinle eko ti mu awon odomode marundinlogun ti won lu jibiti lori ero ayelujara. Oruko awon odaran na ni Adeyemi Tiwatope, 20; Odeyemi Olawale, 20; Nike Afolabi Olaiya, 20; Awe Abimbola Ireti, 23; Yusuf Aliu Oluwafemi, 20; Osidipe Olatunbosun, 24; Tosin Adesanya, 19 and Adeyinka […]

Read The Entire Story Here > Awon osise ajo EFCC gba posi, igba ati opolopo ogun abenugongo lowo awon odomode marundinlogun ton cha-che. (Yahoo boys).

]]>
https://viva-naija.com/awon-osise-ajo-efcc-gba-posi-igba-ati-opolopo-ogun-abenugongo-lowo-awon-odomode-marundinlogun-ton-cha-che-yahoo-boys/feed/ 2 27325
Awon meta lo ku, ti awon meje si farapa ninu ikolu ti awon omo egbe agbesunmomi Bokoharam se ni ilu Maiduguri. https://viva-naija.com/awon-meta-lo-ku-ti-awon-meje-si-farapa-ninu-ikolu-ti-awon-omo-egbe-agbesunmomi-bokoharam-se-ni-ilu-maiduguri/ https://viva-naija.com/awon-meta-lo-ku-ti-awon-meje-si-farapa-ninu-ikolu-ti-awon-omo-egbe-agbesunmomi-bokoharam-se-ni-ilu-maiduguri/#respond Tue, 06 Feb 2018 00:40:05 +0000 https://viva-naija.com/?p=27318 Awon omo egbe agbesunmomi Bokoharam lale ana lo se ikolu ni ilu Maiduguri nibi ti awon eyan meta ti so emi won nu, ti awon meje si farapa. Gege bi atejade ti awon ti oro na se oju won se, won so wipe awon odaran na yabo ilu Koffa, won si bere sini yin ibon, […]

Read The Entire Story Here > Awon meta lo ku, ti awon meje si farapa ninu ikolu ti awon omo egbe agbesunmomi Bokoharam se ni ilu Maiduguri.

]]>
https://viva-naija.com/awon-meta-lo-ku-ti-awon-meje-si-farapa-ninu-ikolu-ti-awon-omo-egbe-agbesunmomi-bokoharam-se-ni-ilu-maiduguri/feed/ 0 27318
Olopa kan yin ibon pa oga re nitori omoge ni ipinle Adamawa. https://viva-naija.com/olopa-kan-yin-ibon-pa-oga-re-nitori-omoge-ni-ipinle-adamawa/ https://viva-naija.com/olopa-kan-yin-ibon-pa-oga-re-nitori-omoge-ni-ipinle-adamawa/#respond Thu, 01 Feb 2018 23:09:42 +0000 https://viva-naija.com/?p=27257 Olopa kan ti oruko re n je , Bala Adamu ni iroyin fi to wa leti wipe o yin ibon pa oga ati olopa akegbe re kan ti oruko re n je Timothy leyin igba ti won mu oti yo ni agbegbe Madagali ni ipinle na. Gege bi atejade ti awon akoroyin Daily Trust se, […]

Read The Entire Story Here > Olopa kan yin ibon pa oga re nitori omoge ni ipinle Adamawa.

]]>
https://viva-naija.com/olopa-kan-yin-ibon-pa-oga-re-nitori-omoge-ni-ipinle-adamawa/feed/ 0 27257
BBNaija 2018; Laarin ojo meji ti idije Big Brother Naija bere, Nina ati Miracle ti bere sini sha ara won je. https://viva-naija.com/bbnaija-2018-laarin-ojo-meji-ti-idije-big-brother-naija-bere-nina-ati-miracle-ti-bere-sini-sha-ara-won-je/ https://viva-naija.com/bbnaija-2018-laarin-ojo-meji-ti-idije-big-brother-naija-bere-nina-ati-miracle-ti-bere-sini-sha-ara-won-je/#respond Tue, 30 Jan 2018 11:42:58 +0000 https://viva-naija.com/?p=27207 Awon oludije meji yi Nina ati Miracle ni ero mohun-maworan gbe nibi ti won tin fi enu ko ara won lenu ninu baluwe. Ojo keji pere re o. Hmmmm  

Read The Entire Story Here > BBNaija 2018; Laarin ojo meji ti idije Big Brother Naija bere, Nina ati Miracle ti bere sini sha ara won je.

]]>
https://viva-naija.com/bbnaija-2018-laarin-ojo-meji-ti-idije-big-brother-naija-bere-nina-ati-miracle-ti-bere-sini-sha-ara-won-je/feed/ 0 27207
Edakun, ema se fun awon olopa ni oti mu. Oga Olopa Edgal Imohimi lo so be. https://viva-naija.com/edakun-ema-se-fun-awon-olopa-ni-oti-mu-oga-olopa-edgal-imohimi-lo/ https://viva-naija.com/edakun-ema-se-fun-awon-olopa-ni-oti-mu-oga-olopa-edgal-imohimi-lo/#respond Fri, 26 Jan 2018 00:08:36 +0000 https://viva-naija.com/?p=27174 Oga olopa Edgal Imohimi leyin akiyesi to se nipa iwa-kiwa ti awon agbofinro to ba mu oti amupara ma n wu, o so wipe lati oni lo, enikeni o gbodo fun olopa kankan ni oti mu mo ai jebe yo fi oju ba ile ejo. O so siwaju si wipe olopa kolopa ti won ba […]

Read The Entire Story Here > Edakun, ema se fun awon olopa ni oti mu. Oga Olopa Edgal Imohimi lo so be.

]]>
https://viva-naija.com/edakun-ema-se-fun-awon-olopa-ni-oti-mu-oga-olopa-edgal-imohimi-lo/feed/ 0 27174
Men are not the problem https://viva-naija.com/men-not-problem/ https://viva-naija.com/men-not-problem/#respond Tue, 23 Jan 2018 12:54:55 +0000 https://viva-naija.com/?p=27079 I got talking with a lady on my upcoming leadership and free skills acquisition program for young ladies, R.E.D. for Girls and she asked me a question, “Why don’t I use ladies as facilitators throughout the program?” She mentioned that if we are dealing with empowering women, then everything needs to be about us as […]

Read The Entire Story Here > Men are not the problem

]]>
https://viva-naija.com/men-not-problem/feed/ 0 27079
Aare orilede nigbakanri oloye Olusegun Obasanjo nse ayeye ikeko gboye Phd ni ile iwe giga National Open University. https://viva-naija.com/aare-orilede-nigbakanri-oloye-olusegun-obasanjo-nse-ayeye-ikeko-gboye-phd-ni-ile-iwe-giga-national-open-university/ https://viva-naija.com/aare-orilede-nigbakanri-oloye-olusegun-obasanjo-nse-ayeye-ikeko-gboye-phd-ni-ile-iwe-giga-national-open-university/#comments Sun, 21 Jan 2018 18:49:57 +0000 https://viva-naija.com/?p=27048 Aare orilede nigbakanri oloye Olusegun Obasanjo nse ayeye ikeko gboye Phd ni ile iwe giga National Open University. Oloye na gba oye Phd ninu eko Christian Theology. Iwuri nla lo je fun awon oluko ati akeko egbe re. Eku orire sir.

Read The Entire Story Here > Aare orilede nigbakanri oloye Olusegun Obasanjo nse ayeye ikeko gboye Phd ni ile iwe giga National Open University.

]]>
https://viva-naija.com/aare-orilede-nigbakanri-oloye-olusegun-obasanjo-nse-ayeye-ikeko-gboye-phd-ni-ile-iwe-giga-national-open-university/feed/ 1 27048
I want to change world’s views about Africa through my lens —Tolani Alli https://viva-naija.com/want-change-worlds-views-africa-lens-tolani-alli/ https://viva-naija.com/want-change-worlds-views-africa-lens-tolani-alli/#comments Fri, 19 Jan 2018 14:23:44 +0000 https://viva-naija.com/?p=27038 When she was asked about what kind of photography she does, she answered saying “limitless photography”. How audaciously witty, that! Well, she’s determined to serve Africa and Nigeria to us in ways never seen before. Let’s meet Tolani Alli, the “limitless” photographer, in this interview with Tribune Nigeria. TOLANI ALLI is a documentary photographer with […]

Read The Entire Story Here > I want to change world’s views about Africa through my lens —Tolani Alli

]]>
https://viva-naija.com/want-change-worlds-views-africa-lens-tolani-alli/feed/ 1 27038
Ajo NYSC ti da eto agunbaniro duro ni ipinle Benue ati Taraba latari ikolu ati ipaniyan ton sele ni awon ipinle na. https://viva-naija.com/ajo-nysc-ti-da-eto-agunbaniro-duro-ni-ipinle-benue-ati-taraba-latari-ikolu-ati-ipaniyan-ton-sele-ni-awon-ipinle-na/ https://viva-naija.com/ajo-nysc-ti-da-eto-agunbaniro-duro-ni-ipinle-benue-ati-taraba-latari-ikolu-ati-ipaniyan-ton-sele-ni-awon-ipinle-na/#respond Mon, 15 Jan 2018 07:10:16 +0000 https://viva-naija.com/?p=26989 Ajo National Youth Service Corps Management ti kede wipe gbogbo awon agunbaniro ti won pin si ipinle Benue ati Taraba ni lati sinmi fun igba die. Ikede yi waye latari ikolu ati ipaniyan ton waye lojojumo ni awon ipinle mejeji yi. Won so siwaju si wipe lai pe, awon a kede ojo tuntun fun eto […]

Read The Entire Story Here > Ajo NYSC ti da eto agunbaniro duro ni ipinle Benue ati Taraba latari ikolu ati ipaniyan ton sele ni awon ipinle na.

]]>
https://viva-naija.com/ajo-nysc-ti-da-eto-agunbaniro-duro-ni-ipinle-benue-ati-taraba-latari-ikolu-ati-ipaniyan-ton-sele-ni-awon-ipinle-na/feed/ 0 26989