Olopa kan yin ibon pa oga re nitori omoge ni ipinle Adamawa.

0

Olopa kan ti oruko re n je , Bala Adamu ni iroyin fi to wa leti wipe o yin ibon pa oga ati olopa akegbe re kan ti oruko re n je Timothy leyin igba ti won mu oti yo ni agbegbe Madagali ni ipinle na. Gege bi atejade ti awon akoroyin Daily Trust se, won so wipe isele na sele nigba ti Timothy ra paraga lowo arabirin kan, eni to je ololufe Adamu, nigbati adamu ri wipe Timothy ati arabirin na eni to je omoge re n ba Timothy soro, inu bi, o si bere si ba ja, lai pe, o muibon re jade, o si yin pa.

Won ti gbe oku Timothy lo si ile igboku si, won si ti mu Adamu ati omoge na lo si atimole awon olopa.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply