Ajo NYSC ti da eto agunbaniro duro ni ipinle Benue ati Taraba latari ikolu ati ipaniyan ton sele ni awon ipinle na.

0

Ajo National Youth Service Corps Management ti kede wipe gbogbo awon agunbaniro ti won pin si ipinle Benue ati Taraba ni lati sinmi fun igba die. Ikede yi waye latari ikolu ati ipaniyan ton waye lojojumo ni awon ipinle mejeji yi. Won so siwaju si wipe lai pe, awon a kede ojo tuntun fun eto na.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply