Edakun, ema se fun awon olopa ni oti mu. Oga Olopa Edgal Imohimi lo so be.

0

Oga olopa Edgal Imohimi leyin akiyesi to se nipa iwa-kiwa ti awon agbofinro to ba mu oti amupara ma n wu, o so wipe lati oni lo, enikeni o gbodo fun olopa kankan ni oti mu mo ai jebe yo fi oju ba ile ejo. O so siwaju si wipe olopa kolopa ti won ba gba mu wipe o mu oti yo na yo fi imu fan ina.

Bakana, o pe akiyesi awon oga olopa kokan lati mojuto gbogbo awon ago olopa ti won dari, lati ri wipe gbogb o awon ton ta oti ninu ago olopa na dekun oti tita.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply