Yoruba News – Viva Naija https://viva-naija.com Never far from home Wed, 14 Feb 2018 14:30:31 +0000 en-US hourly 1 https://wordpress.org/?v=4.9.4 https://i2.wp.com/viva-naija.com/wp-content/uploads/2017/01/Viva_Logo__Pink_Green-e1494690750193.jpg?fit=32%2C24&ssl=1 Yoruba News – Viva Naija https://viva-naija.com 32 32 95230173 #bbnaija; Odomodebirin Cee C ti so akegbe re Tobi di gbewudani. (eni ire lo). https://viva-naija.com/bbnaija-odomodebirin-cee-c-ti-akegbe-re-tobi-di-gbewudani-eni-ire-lo/ https://viva-naija.com/bbnaija-odomodebirin-cee-c-ti-akegbe-re-tobi-di-gbewudani-eni-ire-lo/#respond Fri, 09 Feb 2018 02:13:01 +0000 https://viva-naija.com/?p=27338 Gege bi atejade ti awon ololufe Tobi n se lori ero ayelujara twitter, won tin ke gbajari wipe ki odomodebirin Cee C tu Tobi kale ninu igbekun to fi si. Opolopo awon eyan ton wo idije BBN lon so wipe nkan ton sele laarin awon mejeji ki se oju lasan. Awon atejade ti won se […]

Read The Entire Story Here > #bbnaija; Odomodebirin Cee C ti so akegbe re Tobi di gbewudani. (eni ire lo).

]]>
https://viva-naija.com/bbnaija-odomodebirin-cee-c-ti-akegbe-re-tobi-di-gbewudani-eni-ire-lo/feed/ 0 27338
Awon osise ajo EFCC gba posi, igba ati opolopo ogun abenugongo lowo awon odomode marundinlogun ton cha-che. (Yahoo boys). https://viva-naija.com/awon-osise-ajo-efcc-gba-posi-igba-ati-opolopo-ogun-abenugongo-lowo-awon-odomode-marundinlogun-ton-cha-che-yahoo-boys/ https://viva-naija.com/awon-osise-ajo-efcc-gba-posi-igba-ati-opolopo-ogun-abenugongo-lowo-awon-odomode-marundinlogun-ton-cha-che-yahoo-boys/#respond Tue, 06 Feb 2018 23:46:29 +0000 https://viva-naija.com/?p=27325 Awon osise ajo Economic and Financial Crimes Commission, EFCC, ti ipinle eko ti mu awon odomode marundinlogun ti won lu jibiti lori ero ayelujara. Oruko awon odaran na ni Adeyemi Tiwatope, 20; Odeyemi Olawale, 20; Nike Afolabi Olaiya, 20; Awe Abimbola Ireti, 23; Yusuf Aliu Oluwafemi, 20; Osidipe Olatunbosun, 24; Tosin Adesanya, 19 and Adeyinka […]

Read The Entire Story Here > Awon osise ajo EFCC gba posi, igba ati opolopo ogun abenugongo lowo awon odomode marundinlogun ton cha-che. (Yahoo boys).

]]>
https://viva-naija.com/awon-osise-ajo-efcc-gba-posi-igba-ati-opolopo-ogun-abenugongo-lowo-awon-odomode-marundinlogun-ton-cha-che-yahoo-boys/feed/ 0 27325
Awon meta lo ku, ti awon meje si farapa ninu ikolu ti awon omo egbe agbesunmomi Bokoharam se ni ilu Maiduguri. https://viva-naija.com/awon-meta-lo-ku-ti-awon-meje-si-farapa-ninu-ikolu-ti-awon-omo-egbe-agbesunmomi-bokoharam-se-ni-ilu-maiduguri/ https://viva-naija.com/awon-meta-lo-ku-ti-awon-meje-si-farapa-ninu-ikolu-ti-awon-omo-egbe-agbesunmomi-bokoharam-se-ni-ilu-maiduguri/#respond Tue, 06 Feb 2018 00:40:05 +0000 https://viva-naija.com/?p=27318 Awon omo egbe agbesunmomi Bokoharam lale ana lo se ikolu ni ilu Maiduguri nibi ti awon eyan meta ti so emi won nu, ti awon meje si farapa. Gege bi atejade ti awon ti oro na se oju won se, won so wipe awon odaran na yabo ilu Koffa, won si bere sini yin ibon, […]

Read The Entire Story Here > Awon meta lo ku, ti awon meje si farapa ninu ikolu ti awon omo egbe agbesunmomi Bokoharam se ni ilu Maiduguri.

]]>
https://viva-naija.com/awon-meta-lo-ku-ti-awon-meje-si-farapa-ninu-ikolu-ti-awon-omo-egbe-agbesunmomi-bokoharam-se-ni-ilu-maiduguri/feed/ 0 27318
Olopa kan yin ibon pa oga re nitori omoge ni ipinle Adamawa. https://viva-naija.com/olopa-kan-yin-ibon-pa-oga-re-nitori-omoge-ni-ipinle-adamawa/ https://viva-naija.com/olopa-kan-yin-ibon-pa-oga-re-nitori-omoge-ni-ipinle-adamawa/#respond Thu, 01 Feb 2018 23:09:42 +0000 https://viva-naija.com/?p=27257 Olopa kan ti oruko re n je , Bala Adamu ni iroyin fi to wa leti wipe o yin ibon pa oga ati olopa akegbe re kan ti oruko re n je Timothy leyin igba ti won mu oti yo ni agbegbe Madagali ni ipinle na. Gege bi atejade ti awon akoroyin Daily Trust se, […]

Read The Entire Story Here > Olopa kan yin ibon pa oga re nitori omoge ni ipinle Adamawa.

]]>
https://viva-naija.com/olopa-kan-yin-ibon-pa-oga-re-nitori-omoge-ni-ipinle-adamawa/feed/ 0 27257
BBNaija 2018; Laarin ojo meji ti idije Big Brother Naija bere, Nina ati Miracle ti bere sini sha ara won je. https://viva-naija.com/bbnaija-2018-laarin-ojo-meji-ti-idije-big-brother-naija-bere-nina-ati-miracle-ti-bere-sini-sha-ara-won-je/ https://viva-naija.com/bbnaija-2018-laarin-ojo-meji-ti-idije-big-brother-naija-bere-nina-ati-miracle-ti-bere-sini-sha-ara-won-je/#respond Tue, 30 Jan 2018 11:42:58 +0000 https://viva-naija.com/?p=27207 Awon oludije meji yi Nina ati Miracle ni ero mohun-maworan gbe nibi ti won tin fi enu ko ara won lenu ninu baluwe. Ojo keji pere re o. Hmmmm  

Read The Entire Story Here > BBNaija 2018; Laarin ojo meji ti idije Big Brother Naija bere, Nina ati Miracle ti bere sini sha ara won je.

]]>
https://viva-naija.com/bbnaija-2018-laarin-ojo-meji-ti-idije-big-brother-naija-bere-nina-ati-miracle-ti-bere-sini-sha-ara-won-je/feed/ 0 27207
Edakun, ema se fun awon olopa ni oti mu. Oga Olopa Edgal Imohimi lo so be. https://viva-naija.com/edakun-ema-se-fun-awon-olopa-ni-oti-mu-oga-olopa-edgal-imohimi-lo/ https://viva-naija.com/edakun-ema-se-fun-awon-olopa-ni-oti-mu-oga-olopa-edgal-imohimi-lo/#respond Fri, 26 Jan 2018 00:08:36 +0000 https://viva-naija.com/?p=27174 Oga olopa Edgal Imohimi leyin akiyesi to se nipa iwa-kiwa ti awon agbofinro to ba mu oti amupara ma n wu, o so wipe lati oni lo, enikeni o gbodo fun olopa kankan ni oti mu mo ai jebe yo fi oju ba ile ejo. O so siwaju si wipe olopa kolopa ti won ba […]

Read The Entire Story Here > Edakun, ema se fun awon olopa ni oti mu. Oga Olopa Edgal Imohimi lo so be.

]]>
https://viva-naija.com/edakun-ema-se-fun-awon-olopa-ni-oti-mu-oga-olopa-edgal-imohimi-lo/feed/ 0 27174
Aare orilede nigbakanri oloye Olusegun Obasanjo nse ayeye ikeko gboye Phd ni ile iwe giga National Open University. https://viva-naija.com/aare-orilede-nigbakanri-oloye-olusegun-obasanjo-nse-ayeye-ikeko-gboye-phd-ni-ile-iwe-giga-national-open-university/ https://viva-naija.com/aare-orilede-nigbakanri-oloye-olusegun-obasanjo-nse-ayeye-ikeko-gboye-phd-ni-ile-iwe-giga-national-open-university/#comments Sun, 21 Jan 2018 18:49:57 +0000 https://viva-naija.com/?p=27048 Aare orilede nigbakanri oloye Olusegun Obasanjo nse ayeye ikeko gboye Phd ni ile iwe giga National Open University. Oloye na gba oye Phd ninu eko Christian Theology. Iwuri nla lo je fun awon oluko ati akeko egbe re. Eku orire sir.

Read The Entire Story Here > Aare orilede nigbakanri oloye Olusegun Obasanjo nse ayeye ikeko gboye Phd ni ile iwe giga National Open University.

]]>
https://viva-naija.com/aare-orilede-nigbakanri-oloye-olusegun-obasanjo-nse-ayeye-ikeko-gboye-phd-ni-ile-iwe-giga-national-open-university/feed/ 1 27048
Ajo NYSC ti da eto agunbaniro duro ni ipinle Benue ati Taraba latari ikolu ati ipaniyan ton sele ni awon ipinle na. https://viva-naija.com/ajo-nysc-ti-da-eto-agunbaniro-duro-ni-ipinle-benue-ati-taraba-latari-ikolu-ati-ipaniyan-ton-sele-ni-awon-ipinle-na/ https://viva-naija.com/ajo-nysc-ti-da-eto-agunbaniro-duro-ni-ipinle-benue-ati-taraba-latari-ikolu-ati-ipaniyan-ton-sele-ni-awon-ipinle-na/#respond Mon, 15 Jan 2018 07:10:16 +0000 https://viva-naija.com/?p=26989 Ajo National Youth Service Corps Management ti kede wipe gbogbo awon agunbaniro ti won pin si ipinle Benue ati Taraba ni lati sinmi fun igba die. Ikede yi waye latari ikolu ati ipaniyan ton waye lojojumo ni awon ipinle mejeji yi. Won so siwaju si wipe lai pe, awon a kede ojo tuntun fun eto […]

Read The Entire Story Here > Ajo NYSC ti da eto agunbaniro duro ni ipinle Benue ati Taraba latari ikolu ati ipaniyan ton sele ni awon ipinle na.

]]>
https://viva-naija.com/ajo-nysc-ti-da-eto-agunbaniro-duro-ni-ipinle-benue-ati-taraba-latari-ikolu-ati-ipaniyan-ton-sele-ni-awon-ipinle-na/feed/ 0 26989
Alase ati oludari Facebook. Ogbeni Mark Zuckerberg ti ya sare pa owo toto Billionu merin dollar ($4 Billion) ni odun 2018. O GA O! https://viva-naija.com/alase-ati-oludari-facebook-ogbeni-mark-zuckerberg-ti-ya-sare-pa-owo-toto-billionu-merin-dollar-4-billion-ni-odun-2018-o-ga-o/ https://viva-naija.com/alase-ati-oludari-facebook-ogbeni-mark-zuckerberg-ti-ya-sare-pa-owo-toto-billionu-merin-dollar-4-billion-ni-odun-2018-o-ga-o/#respond Thu, 11 Jan 2018 12:07:30 +0000 https://viva-naija.com/?p=26967 Odomode kunrin, alase ati oludari Facebook, ogbeni Mark Zuckerberg ti ninu odun yi pa owo toto billonu merin dollar ninu odun tuntun 2018 ta sese mu yi. Gbohun mi, baba gbohun mi.

Read The Entire Story Here > Alase ati oludari Facebook. Ogbeni Mark Zuckerberg ti ya sare pa owo toto Billionu merin dollar ($4 Billion) ni odun 2018. O GA O!

]]>
https://viva-naija.com/alase-ati-oludari-facebook-ogbeni-mark-zuckerberg-ti-ya-sare-pa-owo-toto-billionu-merin-dollar-4-billion-ni-odun-2018-o-ga-o/feed/ 0 26967
Egbe agbaboolu Arsenal ti fo’rijagbo leyin igba ti Egbe agbaboolu Nottingham Forest foju won ri mabo ninu idije FA cup to waye lana. https://viva-naija.com/egbe-agbaboolu-arsenal-ti-forijagbo-leyin-igba-ti-egbe-agbaboolu-nottingham-forest-foju-won-ri-mabo-ninu-idije-fa-cup-waye-lana/ https://viva-naija.com/egbe-agbaboolu-arsenal-ti-forijagbo-leyin-igba-ti-egbe-agbaboolu-nottingham-forest-foju-won-ri-mabo-ninu-idije-fa-cup-waye-lana/#respond Mon, 08 Jan 2018 11:10:04 +0000 https://viva-naija.com/?p=26907 Egbe agbaboolu Arsenal fidi remi lana ninu idije FA CUP to waye laarin akegbe won Nottingham Forest. Omi ayo merin si meji (4-2)ni awon egbe agbaboolu Arsenal je ti won si mu omi si. Agbaboolu Eric Lichaj, Per Mertesacker, Ben Brereton ati Kieran Dowell lo gba omi ayo wole fun egbe agbaboolu Nottingham forest, ti […]

Read The Entire Story Here > Egbe agbaboolu Arsenal ti fo’rijagbo leyin igba ti Egbe agbaboolu Nottingham Forest foju won ri mabo ninu idije FA cup to waye lana.

]]>
https://viva-naija.com/egbe-agbaboolu-arsenal-ti-forijagbo-leyin-igba-ti-egbe-agbaboolu-nottingham-forest-foju-won-ri-mabo-ninu-idije-fa-cup-waye-lana/feed/ 0 26907