Aku ayeye odun ominira orilede Nigeria o!. Emi wa o se pupo re la’ye o.

0

 

Oni, ojo kini osu kewa lo pe odun ketadinlogota ti orilede Nigeria gba ominira lowo awon oyinbo alawo funfun. Opolopo eto idagbasoke ati ilosiwaju lo ti sele lati igba ti a ti gba ominira yi, beeni opolopo idamu ati isele ajalu buuruku lo ti sele ni orilede yi pelu.

Adura wa ni wipe ki olorun tunbo di orilede yi mu, ki o si fun wa ni awon adari to je eni bi okan re lati le gbe orilede yi de ibi ti eru o ti ni ba wa mo. Amin

Aku ayeye odun ominira o.

 

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply