Gomina ipinle Eko, Akinwumi Ambode ti pase wipe ki gbogbo awon ile eko ti...

Gomina ipinle Eko, Akinwumi Ambode ti pase wipe ki gbogbo awon ile eko ti ijoba ati aladani ni ipinle na ma ko awon akeko ni orin adako orilede (National Anthem) ni ede Yoruba. O...

Iyawo Aare orilede arabirin Aisha Buhari gba awon obirin ninu egbe oloselu APC lalejo...

Iyawo Aare orilede arabirin Aisha Buhari loni gba awon obirin to je omo egbe oloselu APC lalejo loni ni ile Aare to wa ni ilu Abuja. Idi ipade yi da le lori ifowosowopo awon...

Idunu ati ayo ni Aare Buhari fi pade omokunrin re Yusuf, eni to sese...

Ogbeni Yusuf, eni to lo gba itoju to peye ni orilede Germany latari ijamba okada to ni ni nkan bi osu meji seyin, lo ti pada de orilede Nigeria ni ayo ati alafia. Idunu...

#BBNaija; Ogbeni Tobi ti dibo lati le arabirin Cee C kuro ninu idije Big...

Iyalenu nla lo je nigba fun gbogbo awon oluworan idije Big Brother Naija loni nigba ti ogbeni Tobi dibo yan arabirin Cee C ati Lolu kuro ninu idije na, to si fi arabirin BamBam...

Kayefi nla lo je nigba ti ejo abami kan gbe millionu mẹ́rìndínlógójì (36million naira)...

Iroyin fi to wa leti wipe ejo abami  kan gbe owo to to millionu mẹ́rìndínlógójì mi ninu ile ise JAMB to wa ni ilu Markurdi, ni ipinle Benue. Awa ke si gbogbo awon ode...

#bbnaija; Odomodebirin Cee C ti so akegbe re Tobi di gbewudani. ...

Gege bi atejade ti awon ololufe Tobi n se lori ero ayelujara twitter, won tin ke gbajari wipe ki odomodebirin Cee C tu Tobi kale ninu igbekun to fi si. Opolopo awon eyan ton...

Awon osise ajo EFCC gba posi, igba ati opolopo ogun abenugongo lowo awon odomode...

Awon osise ajo Economic and Financial Crimes Commission, EFCC, ti ipinle eko ti mu awon odomode marundinlogun ti won lu jibiti lori ero ayelujara. Oruko awon odaran na ni Adeyemi Tiwatope, 20; Odeyemi Olawale,...

Awon meta lo ku, ti awon meje si farapa ninu ikolu ti awon omo...

Awon omo egbe agbesunmomi Bokoharam lale ana lo se ikolu ni ilu Maiduguri nibi ti awon eyan meta ti so emi won nu, ti awon meje si farapa. Gege bi atejade ti awon ti...

Olopa kan yin ibon pa oga re nitori omoge ni ipinle Adamawa.

Olopa kan ti oruko re n je , Bala Adamu ni iroyin fi to wa leti wipe o yin ibon pa oga ati olopa akegbe re kan ti oruko re n je Timothy leyin...

BBNaija 2018; Laarin ojo meji ti idije Big Brother Naija bere, Nina ati...

Awon oludije meji yi Nina ati Miracle ni ero mohun-maworan gbe nibi ti won tin fi enu ko ara won lenu ninu baluwe. Ojo keji pere re o. Hmmmm  

Stay Connected

38,098FansLike
28FollowersFollow
18,335FollowersFollow
3,546FollowersFollow
84SubscribersSubscribe