Gbajugbaja odomodebirin olorin Tiwa Savage ti fakoyo nigba to gba emi eye nibi ayeye...

Odomodebirin olorin Tiwa Savage ti gbegba oroke nibi ayeye MTV European Music Awards nigba to fakoyo, to si gba ami eye eni to mo orin ko julo nile adulawo (Best African Act) . Odomodebirin na...

Leyin opolopo igbiyanju, Aare Buhari ti gba iwe eri idanwo WAEC (AYO ABARA...

AareBuhari loni gba alejo awon oga agba ajo WAEC lati gba iwe eri idanwo WAEC re to se. Idunu ati ayo ni Aare Buhari fi gba won lalejo ninu ile Ijoba towa ni ilu Abuja....

Apapo egbe awon osise (NLC) ti pinu lati gun le iyanselodi lati ojo kefa...

Ajo apapo egbe awon osise (NLC) ti pinu lati gun le eto iyanselodi lati ojo kefa osu kokanla ti ijoba apapo ba ko lati fi owo kun owo osu awon osise ijoba ni orilede...

Olori Alaafin Oyo, (IKU BABA-YEYE) tun ti bi ibije lanti-lanti

Epo n'be Ewa n'be ni orin ti won ko ni aafin Alaafin Oyo (Iku baba-yeye) lati ibere odun yi. Eyi waye latari awon omo ibeji ti awon olori laafin tin bi. Olori Anu ni olori...

Awon agbofinro ti bere iwadi lori iku omidan Seun Ajila

Leyin iku omidan Seun Ajila, eni ti won fi ipa balo ti won si da emi re legbodo ni ojo kerin osu kewa ni ile re ni ilu Akure ni awon agbofinro ti bere...

Aworan nibi ayeye igbeyawo laarin Ooni Ife Oba Adeyeye Ogunwusi ati ajihinrere Naomi Oluwaseyi

Ayeye igbeyawo tunutn ti waye laafin Ooni Ile Ife, Oba Adeyeye Ogunwusi leyin igba ti igbeyawo re forisanpon pelu olori nigbakan ri Wuraola ni nkan bi odun kan seyin. Igbeyawo na waye laarin Kabiyesi...

Ajo INEC ti yan Oludije labe egbe oloselu APC Gboyega Oyetola gege bi eni...

Oludije fun ipo Gomina ipinle Osun labe egbe oloselu APC ti gbe igba oroko ninu eto idibo to waye ni ipinle na loni. Leyin gbogbo atotonu ati igbiyanju egbe oloselu PDP lati fakoyo ninu eto...

Aare ile igbimo asofin Bukola Saraki se ipade pelu Iyiola Omisore loni ni ile...

Aare ile igbimo asofin, Bukola Saraki loni lo se abewo ati ipade pelu oludije fun ipo Gomina ipinle Osun labe egbe oloselu SDP loni ni ilu ile Ife. Ipade na da lori bi egbe oloselu...

Alai mo ore lasan-lasan ni ‘K1 De Ultimate’- Obesere lo so be

Gbajugbaja olorin Fuji ati ogbontarigi osere tiata Abass Akande Obesere ninu atejade kan to se lori oro ija to waye laarin Alhaji Wasiu Ayinde ati Gomina ipinle Eko Akinwumi Ambode so wipe alai mo...

Ogbeni Fela Durotoye ti gba iwe ase lati egbe oloselu ANN lati tesiwaju ninu...

Oludije fun ipo Aare, Ogbeni Fela Durotoye ti gba iwe ase lati egbe oloselu ANN lati tesiwaju ninu ipinu re lati dije fun ipo Aare ni odun 2019. Eyi ti fi ipinu Ogbeni Durotoye...