Home Authors Posts by Kolly_Moore

Kolly_Moore

Kolly_Moore
139 POSTS 12 COMMENTS
My name is Adenle Kolade Samuel, I am a Yoruba news and lifestyle Blogger,Owner of www.kollymoore.blogspot.com. Studied Linguistics and Nigerian Languages at University of Ilorin,graduated in 2014, currently studying Mass communication in Kwara State University. I started blogging in 2015 with the passion and love for Yoruba language. I want everyone to know that there is uniqueness in being real and truthful to yourself and that God has given everyone a duty to promote his/ her culture.

Arakunrin Olubankole Wellington (Banky W) ti fi ipinu re han lati dije gege bi...

Arakunrin Olubankole Wellington (Banky W) ti fi ipinu re han lati dije gege bi asoju ile igbimo asofinfun awon ara Eti Osa asofin labe egbe oloselu Modern Democratic Party. Gbajugbaja osere ati olorin na...

#El-Zakzaky3.5million Opuro aye ati orun ni Lai Mohammed- Reno Omokri lo so be

Ogbeni Reno Omokri ninu atejade to se lori ero ayelujara twitter loni lo ti bu enu ate lu atejade kan ti ogbeni Lai Mohammed se nigba ton ba awon akoroyin soro. Ninu faran na, ni...

Gbajugbaja odomodebirin olorin Tiwa Savage ti fakoyo nigba to gba emi eye nibi ayeye...

Odomodebirin olorin Tiwa Savage ti gbegba oroke nibi ayeye MTV European Music Awards nigba to fakoyo, to si gba ami eye eni to mo orin ko julo nile adulawo (Best African Act) . Odomodebirin na...

Leyin opolopo igbiyanju, Aare Buhari ti gba iwe eri idanwo WAEC (AYO ABARA...

AareBuhari loni gba alejo awon oga agba ajo WAEC lati gba iwe eri idanwo WAEC re to se. Idunu ati ayo ni Aare Buhari fi gba won lalejo ninu ile Ijoba towa ni ilu Abuja....

Gbajugbaja odomode olorin WizKid ati akegbe re Tiwa Savage ti se obe alata suwe-suwe

Ninu afihan agbejade mohun-maworan (fidio)kan ti odomode kunrin olorin WIZ KID sese gbejade to pe akole re ni FEVER ni akegbe re Tiwa Savage ti gbe laruge ti won si jo fi ife jan...

Apapo egbe awon osise (NLC) ti pinu lati gun le iyanselodi lati ojo kefa...

Ajo apapo egbe awon osise (NLC) ti pinu lati gun le eto iyanselodi lati ojo kefa osu kokanla ti ijoba apapo ba ko lati fi owo kun owo osu awon osise ijoba ni orilede...

Olori Alaafin Oyo, (IKU BABA-YEYE) tun ti bi ibije lanti-lanti

Epo n'be Ewa n'be ni orin ti won ko ni aafin Alaafin Oyo (Iku baba-yeye) lati ibere odun yi. Eyi waye latari awon omo ibeji ti awon olori laafin tin bi. Olori Anu ni olori...

Awon agbofinro ti bere iwadi lori iku omidan Seun Ajila

Leyin iku omidan Seun Ajila, eni ti won fi ipa balo ti won si da emi re legbodo ni ojo kerin osu kewa ni ile re ni ilu Akure ni awon agbofinro ti bere...

Aworan nibi ayeye igbeyawo laarin Ooni Ife Oba Adeyeye Ogunwusi ati ajihinrere Naomi Oluwaseyi

Ayeye igbeyawo tunutn ti waye laafin Ooni Ile Ife, Oba Adeyeye Ogunwusi leyin igba ti igbeyawo re forisanpon pelu olori nigbakan ri Wuraola ni nkan bi odun kan seyin. Igbeyawo na waye laarin Kabiyesi...

Ajo INEC ti yan Oludije labe egbe oloselu APC Gboyega Oyetola gege bi eni...

Oludije fun ipo Gomina ipinle Osun labe egbe oloselu APC ti gbe igba oroko ninu eto idibo to waye ni ipinle na loni. Leyin gbogbo atotonu ati igbiyanju egbe oloselu PDP lati fakoyo ninu eto...