Gbajugbaja odomode olorin Small Doctor ti gba Penalty lo Throw in o!

0

Odomode olorin small doctor ni o se afihan aworan re nibi to ti n fi nkan omokunrin re sere (wanking) lori ero ayelujara whatsapp. Awon eyan so wipe asise ni eleyi je, nitoripe orebirin re kan lo ni lokan lati fi aworan na sowo si.

Eyi lo mu awon omo Nigeria ati awon ololufe odomode olorin na so wipe o ti gba penalty lo Throw in gege bi orin re to sese ko.

Atejade ti awon omo Nigeria se ni yi ni ede geesi, lori ero ayelujara twitter;

See how Nigerian Twitter is reacting to the news below…

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply