Gomina ipinle Imo Rochas Okorocha fi Aare orilede South Africa Jacob Zuma je oye ni ipinle na.

0

 

Aare orilede South Africa Jacob Zuma ti je oye Ochiagha Imo ni ipinle Imo ni ana. Eze Imo, HRH Samuel Ohiri Owerri, ti ipinle Imo lo fi Aare na je oye na, to si gbe ami eye na le Aare orilede Nigeria nigbakan ri Oloye Olusegun Obasanjo lowo lati gbe fun Aare Jacob Zuma.

Eyi waye nibi abewo olojo meji ti Aare orilede South Africa se si ipinle Imo, fun ajosepo to wa laarin Rochas Okorocha Foundation ati Jacob Zuma Foundation eyi ti won gbe kale lati fun awon omo Africa ni eko to te koro lofe.

 

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply