Aare Muhammadu Buhari ti pase fun awon Gomina ipinle lati san gbogbo owo osu awon osise ti won je ki odun Keresi to wole de.

5

Aare Muhammadu Buhari ni ojo aje, ojo ketadinlogun osu kokanla pase fun gbogbo awon Gomina ipinle lati ri wipe won san gbogbo owo osu awon osise ti won je ki odun keresi to wole de.

Aare pa ase yi nigba ton se ipade pelu awon Gomina ipinle ni ile ijoba to wa ni Abuja. Agbenuso Aare Buhari lori ero ayelujara ogbeni Basir Ahmad lo se atejade yi nigba ti ipade na n’lo lowo. 

 Atejade ti arakunrin na se ni yi ni ede geesi;

“President Muhammadu Buhari during the meeting with state governors, charged them to ensure that they pay all the salaries owed workers before Christmas.”

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

5 COMMENTS

Leave a Reply Cancel reply