Awon omo egbe agbaboolu Nigeria (Super Eagles) fi oju egbe agbaboolu Argentina gbole nigba ti won na won ni omi ayo merin si meji 4:2.

0

Awon omo egbe agbaboolu Super Eagles ninu idije to waye laarin won ati awon omo egbe agbaboolu Argentina ni ilu Krasnodar, ni orilede Russia ni won ti fi oju won gbole nigba ti won na won ni omi ayo merin si meji. Alex Iwobi, Kelechi Ihenacho ati Brian Idowu lo gba awon ayo na wole fun Nigeria ti Ever Banega ati Sergio Aguero gba omi ayo wole fun orilede Argentina.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply