Egungun kan pada si orun nigba ti oko ayokele kan gba ni ipinle Akwa Ibom.

1

Awako kan ni oju opopona Nwaniba Road ni Use Offot, Uyo, ni ipinle Akwa Ibom gba ara orun kan ti o si gba emi re. Gege bi iwadi, awon ti oro na se oju won so wipe awako na lon sa ere bo, to si yi owo oko re lati le ma gba awako miran ton bo, sugbon o gba egungun ton jo loju opopona na ti egungun na si ku leskese.

Awon eleso abo ilu ti wa gbe oku egungun yi lo si ite igbokusi, awon agbofinro si ti bere iwadi lati mo awako to wa oko na.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

1 COMMENT

Leave a Reply