Gomina Nasir El-Rufia lo ki ojise Olorun Tunde Bakare leyin igba to gbo wipe Olorun so fun lati dije fun ipo Aare orilede Nigeria.

0

Gomina ipinle Kaduna Nasir El-Rufai loni lo se abewo si ojise Olorun Tunde Bakare ni ijo re to wa ni ipinle Eko Latter Rain Assembly ni oni, ojo keje osu kini. Abewo yi waye leyin ojo meji ti ojise Olorun na fi han wipe Olorun ti ba ohun soro lati dije fun ipo Aare orilede Nigeria.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply