Olori nigbakan ri arabirin Zainab Obanor ti jewo wipe ohun ti kuro ni afin Ooni Adeyeye Ogunwusi.

0

Gege bi atejade ti arabirin Zainabu se lori ero ayelujara instagram, o so wipe looto ni igbeyawo ohun ati Ooni Adeyeye ti dopin. O so siwaju si wipe ki eni kankan ma so oro odi si ohun latari isele to sele yi, wipe Olorun nikan lo le dajo.

Atejade to se ni yi ni ede geesi;

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply