Amir, omo Sultan ti ilu Sokoto ti farapa ninu ijamba oko

0

Isele ijamba oko kan to waye ni nkan bi ago mejila ni iroyin fi to wa leti wipe Amir, omo Sultan ilu Sokoto ti farapa yana-yana.

Gege bi oro ti awon ti oro na se oju won,ati awon akoroyin Sahara Reporters so, won so wipe arakunrin na ati awon ore re meji Khalifa Maccido ati odomode birin kan ni won wa ninu oko na, ti iwadi si fi han wipe won ti mu oti ati ohun oloro yo.

Wayi, Won ti gbe won lo si ile iwosan Usman Danfodio Teaching Hospital fun itoju to peye.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply