Awon agbebon kan ti ji ojise Olorun ijo Katoliki mimo kan gbe ni ipinle Delta

0

Ojise Olorun Christopher Ogaga ti ijo Katoliki mimo Emmanuel Catholic Church Oviri-Okpe ni ilu Okpe, ipinle Deltani iroyin fi to wa leti wipe awon agbebon kan ti ji gbe.

Ojise Olorun na, eni to tun je alamojuto ile iwe St. Peters Clavers College, Aghalokpe ni won ji gbe ni ojo keji osu kejo, nigba ton lo si ile ijosin Redeemer Catholic Church, ni opopona Airport junction, ni Effurun. Iwadi to peye ti bere lori oro na. Awon ajinigbe na si ti bere owo itanran toto millionu marundinlogun naira.

Oga olopa ton soju ipinle Delta, ogbeni Muhammad Mustafa na ti fi idi oro na mule, o si ti se ileri lati sa gbogbo ipa re lati ri wipe won ri ojise Olorun na pada.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply