Idunu ati ayo ni Aare Buhari fi pade omokunrin re Yusuf, eni to sese de lati orilede Germany fun itoju to peye.

0

Ogbeni Yusuf, eni to lo gba itoju to peye ni orilede Germany latari ijamba okada to ni ni nkan bi osu meji seyin, lo ti pada de orilede Nigeria ni ayo ati alafia. Idunu ati ayo ni Aare Buhari fi ki omokunrin re na kaabo pada si orilede yi, to si dupe lowo Olorun fun ore ofe re lori aye re.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply