Oludije fun ipo Aare; Arakunrin Fela Durotoye ati Ogbeni Omoyele Sowore latari akitiyan won lati gbe orilede Nigeria ga ti pinu lati fi owo sowopo ninu eto idibo ton bo ni odun 2019

1

Arakunrin Fela Durotoye ati ikan gboogi ninu awon akegbe re Ogbeni Omoyele Sowore ti pinu lati fowosowopo ninu akitiyan won lati du ipo Aare orilede Nigeria ni odun 2019. Eyi waye latari ife won fun orilede yi ati lati gbe orilede na ga de ebute yinyanju.

Arakunrin Fela Durotoye ninu atejade kan to se lori ero ayelujara twitter fi idi oro na mule, o si fi opolopo awon aworan ka oro na ni idi.

Atejade na ni yi ni ede geesi;

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply