Agba-oje osere ati akowe, Baba Adebayo Faleti ti ku. (YORUBA ICON)

1

Agba-oje ninu ere itage, gbajugbaja osere ati eni akoko to tunmo orin aroko orilede (National Anthem and Pledge) Nigeria lati ede Geesi si ede Yoruba ti ku. Baba Adebayo faleti eni to gba orisirisi ami eye ni orilede yi ati ni oke okun lo ku ni aro kutukutu ojo kejilelogun osu keje odun 2017 ni ile iwosan ijoba ti University College Hospital to wa ni ilu Ibadan. Baba Adebayo faleti ko ipa ribiribi ninu gbigbe asa ati ede Yoruba laruge.

Omo odun mefalelogorin (86years) ni baba ki olojo to de.

Adura wa ni wipe ki Olorun te baba na si afefe ire. Amin.

 

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

1 COMMENT

Leave a Reply Cancel reply