Alase ati oludari eto sogun-dogoji MMM, ogbeni Sergei Mavrodi ti ku. (Aye mo juba o).

0

Alase ati oludari eto sogun-dogoji ti opolopo awon omo Nigeria ti so owo won nu ti ku. Iroyin fi towa leti wipe arakunrin na lo so emi re nu ni ile iwosan leyin igba to kigbe wipe aya n ro ohun. Omo odun mejilelogota ni arakunrin na ki olojo to de.

Get more stuff like this
in your inbox

Subscribe to our mailing list and get interesting stuff and updates to your email inbox.

Thank you for subscribing.

Something went wrong.

Leave a Reply Cancel reply